Olamide ogunade charcoal artist: bí mo ṣe ń lo ẹrọ ayélujára fi ran títa àwòrán mi lọ́wọ́ - bbc news yorùbá

Play all audios:

OLAMIDE OGUNADE CHARCOAL ARTIST: BÍ MO ṢE Ń LO ẸRỌ AYÉLUJÁRA FI RAN TÍTA ÀWÒRÁN MI LỌ́WỌ́ 24 Ẹrẹ̀nà 2021 OLAMIDE OGUNADE JẸ ỌDỌ AMỌ O TUN DA YỌTỌ LARIN AWỌN ỌDỌ FUN IRU IṢẸ ỌWỌ ARA ỌTỌ TO N
ṢE. O jẹ eeyan to maa n ronu tayọ nkan ti oju n ri eyi to si maa n fi awonran rẹ ṣalaye fun awọn eniyan. Lati kekere ni Olamide ti ri ẹbun yii ninu ara rẹ to si jara mọ ọ lai ṣe iye meji. *
'Ǹkan tó jẹ́ kí iṣẹ́ ọ̀nà tèmi yàtọ̀ lágbàáyé ni ǹkan tí mò ń lò' * Ọ̀nà láti dín paǹtí irin kù ló sọ mí di agbẹ́rinlére aláṣeyọrí- Oladele Ogbeyemi * Wo àwọn ọ̀rọ̀ tó ki pọ́pọ́
tí Lateef Adedimeji fi kọrin ọjọ́ ìbí 23 fún Adebimpe Oyebade "Onítèmi" "Iṣẹ ọna ni ṣe pẹlu wiwa ọna ati ba awọn eeyan sọrọ, mo maa n woye kikun aworan gẹgẹ ọ̀rọ̀ sisọ laarin
rẹ ati eeyan to n wo aworan naa". Iwuri ni iṣẹ aworan yiya Olamide yii to si ni o ti gbe oun jade kuro lorilẹede Naijiria lọ si Dubai amọ ọja ọhun naa ko ya lorilẹede Naijiria. O mẹnu
ba ipa ti ayelujara n ko ninu tita ọja rẹ gẹgẹ bi eyi to dara gidi. Iyalẹnu ni wipe ikọwe pencil ati eedu ni Olamide fi n ya awọn aworan rẹ. Olamide naa gẹgẹ bi ọdọ Naijiria tẹnu mọ ọ pe ọrọ
oṣelu ati ipo ti ọrọ aje Naijiria wa jẹ ọkan lara ohun to n ṣakoba fun iṣẹ rẹ. * Ìdìbò ọdún 2023 leè má wáyé bí ìjọba kò bá yanjú ìpèníjà ààbò - Akeredolu * Ẹnikẹ́ni tó bá fa wàhálà míì
lẹ́yìn rògbòdìyàn ọ̀rọ̀ Hijab tó wáyé n'Ilorin yóò fojú winá òfin - AbdulRazaq * Ẹ̀yà Yorùbá ti fara ṣiṣẹ́ púpọ̀ fún Naijiria, nítorí nàá à kò le déèdé sọ pé a fẹ́ kúrò - Àgbààgbà
Yorùbá * Sùkẹ̀! Ọ̀rọ̀ òṣèlú ni gbogbo ẹ tí Akeredolu ṣe tako ìdásílẹ̀ Oduduwa Nation - Banji Akintoye